DAMILOLA OLUBORODE retweeted
The place where the sea split into two like in the story of Moses. Ibi tí òkun tí máa ń pín sí méjì bíi ti ìtàn Móósè
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
Do you have asbestos in your house? Please watch. Njẹ ẹ ní abestọ nínú ilé yin? Ẹ wo fọ́nrán yí.
Full video (fọ́nrán kíkún): #049
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
Moon phases in Yoruba. This is why the moon is big sometimes, while it is small at other times. Ipele osupa ni Yoruba. Idi ni yi ti osupa fi maa n tobi lawọn igba kan to si maa n kere lawọn igba mii
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
Do you cook with gas? Watch this and share. Se ẹ maa n dana pẹlu fẹlẹlẹ? E wo ẹyi ki ẹ si pin-in ka.
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
How you can help this research move fast. Bi ẹ ṣe le ran iṣẹ iwadi yi lọwọ ko le tete tẹ siwaju.
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
This guy is here to stay. Get used to him Excelmathematics Yoruba. We all must Learn Mat and sciences (phy chem bio) in Yoruba😇
That’s my vision becoming a Reality in my lifetime.🔥
#teachinyoruba
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
Ẹ ran iṣẹ iwadi yi lọwọ. Ẹ ba wa mu ọrọ Yoruba kan fun tyre. Ẹ ṣeun pupọ – at Ikeja, Nigeria
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
New research alert: How you can prevent crying when cutting onions. Iṣe iwadi tuntun: Ọna ti ẹ le gba lati dena ẹkun sisun nigba ti ẹ ba n ge alubọsa
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
"Two waters that do not mix." Here are the facts. "Awọn omi meji ti wọn o wọ inu ara wọn." Okodoro ọrọ niyi. – at Ikeja, Nigeria
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
In my lifetime, Yoruba will be approved as the major language of instruction across Yorubaland.🔥
I have the conviction. Who else is with me on this✍🏽👀
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
This is the lie you
are told every day. Irọ ti ẹ n ba pade lojoojumọ niyi.
DAMILOLA OLUBORODE retweeted
How long did it take Felix to jump from "space"? Iye iṣẹju melo lo gba Felix lati bẹ silẹ lati inu gbalasa ofuurufu?










